Ọmọbọlanle Aṣabi Sarumi aya Aliyu ni obinrin akọkọ ti yoo jade lati du ipo gomina nipinlẹ Ọyọ.
Aliyu ni awọn obinrin to n gbe awọn ọkunrin de ipo giga lati ọdun gbọọrọ naa lẹtọ lati du ipo oselu, ki wọn si ri atilẹyin awọn ọkunrin yii.
O wa gba awọn akẹẹgbẹ lobinrin nimọran lati ṣe atilẹyin fawọn obinrin ẹlẹgbẹ wọn, kawọn obinrin lee ko ida marundinlogoji ti awujọ agbaye ni o yẹ ki wọn ni ninu oselu sise.