Home Crime #ENDSARS: Awọn Odaràn Yóò Ní Agbára Láti Siṣẹ́ Ibi Púpọ̀

#ENDSARS: Awọn Odaràn Yóò Ní Agbára Láti Siṣẹ́ Ibi Púpọ̀

1552
0•Shogunle Ni Iṣẹ́ SARS Pọ̀ Lásìkò Yìí Kọjá Aríwísí

Ọgá ọlọ́pàá Abayomi Shogunle woye pe kosi idi kan gboogi lati ko awọn ọlọpaa kogberegbe SARS kuro nilẹ gẹgẹ bi ọpọ eeyan ti n pariwo.


Ọgá ọlọ́pàá naa to ba ile iṣẹ Iroyin BBC Yoruba sọrọ ni pe awọn ti wọn n sọ pe ki ijọba ko SARS nilẹ ko ni ẹri kankan lati fi idi ẹsun wọn mulẹ.

O fi kun ọrọ rẹ pe ọdaran yoo gbode kan ti ijọba ba ko ọlọpaa SARS nilẹ.

Leave a Reply