Home News Ìjàmbá Iná Èkó: Èèyàn Méjìlá Ló Ti Kú Báyìí

Ìjàmbá Iná Èkó: Èèyàn Méjìlá Ló Ti Kú Báyìí

1163
0

Ijọba Ipinlẹ Eko sọ pe o ti di eeyan mejila ti wọn ti padanu ẹmi wọn ninu ijamba ina to ṣẹlẹ lọṣẹ to kọja.

Kọmiṣọna fun eto ilera, Dokita Jide Idris lo ṣalaye ọrọ yii l’Eko lọjọ Aje.

Google search engine

Google search engine

Eeyan mẹsan n’iroyin kọkọ gbe pe wọn ku lẹyin ti ijamba naa ṣẹlẹ, ṣugbọn dokita Idris ṣalaye pe awọn mẹwa lo ku gbara ti iṣẹlẹ ọ̀hún ṣẹlẹ, ti awọn meji si papoda nile iwosan.

Ẹwẹ, ijọba Ipinlẹ Eko ti kede pe ki ẹnikẹni to ba fura pe awọn ẹbi wọn wa lara awọn to padanu ẹmi wọn ninu ijamba ina naa kàn si ile-iṣẹ ijọba to n ri si ayẹwo DNA ati iwadii.

Ile-iṣẹ naa wa ni opopona Broad Street, to dojukọ ile itawe ni agbegbe CMS, ni Erekusu ilu Eko.

Previous article#ENDSARS: Awọn Odaràn Yóò Ní Agbára Láti Siṣẹ́ Ibi Púpọ̀
Next article1,500 Ibadan Residents To Benefit From Sunday Dare’s Free Eye Glasses Initiative

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here