Iròyìn tó ń tẹ̀ www.oyoinsight.com lọ́wọ́ ni àwọn alápatà takú láti tẹ̀lé àsẹ ìjọba pé kí wọn kó lọ sí ọjà ẹran tuntun, àmọ́ tí wọn yarí.
Ìdí nìyí tí ìjọba se kó àwọn ọlọ́pàá lọ sí ọjà Bódìjà láti pé wọn tẹ̀lé àsẹ ìjọba, sùgbọ́n tí ọ̀rọ̀ náà bọ́wọ́ sórí.
A n se akojọpọ ẹkunrẹrẹ iroyin yajoyajo lọwọ, a o maa gbe ẹkunrẹrẹ iroyin naa sori atẹ iroyin wa laipẹ. Ẹ jọwọ, ẹ tun oju opo iroyin yi yẹwo, ki ẹ lee ri ẹkunrẹrẹ iroyin ọtun laipẹ.