Home News Iná Èkó: Kò Sí Eni To Le Dá Okú Rẹ Mọ̀

Iná Èkó: Kò Sí Eni To Le Dá Okú Rẹ Mọ̀

1095
0

Ìyàlẹ́nu ló jé lósàn ọjọ́ kejì tí ìsẹ̀lẹ̀ náà wáyé, nígbàti BBC Yorùbá sàbẹ̀wò sí ibùdó igbókúsí ilé ìwòsàn Mainland pé, àwọn ebí àwọn tó kú nínú ìjàmbá iná orí afárá ọtẹ́dọlá, tí kúrò níbẹ̀.

Awọn òṣìṣẹ́ náà sàlàyé pé, gbogbo àwọn òkú tí wọ́n gbé wá sibẹ̀ jóná kọjá ídámọ̀, èyí ló fáà tí wọn kò se gba ẹbi kankan láàyè láti gbe okú lọ̀, títí ti Gomina ìpínlẹ̀ Eko, Akinwumi Ambode yoo fi kéde bóya wọn yóò sín àwọn okú náà pọ̀ ní abi bẹ́ẹ̀kọ́.Síbẹ̀ ọ̀pọ̀ àwọn ebí ló bo ilé ìwòsàn Mainland bibà, lati wá àwọn olólùfẹ́ wọn.

Leave a Reply