Tag: #Samuel Ladoke Akintola
Samuel Ladoke Akintọla: Awọn Ohun To Yẹ Ko Mọ Nipa E
Samuel Ladoke Akintọla jẹ ojulowo ọmọ Yoruba to ko ipa manigbagbe ni saa isejọba alagbada akọkọ ni orilẹede Naijiria.
Agba ọjẹ oloselu ni Akintọla, to...