Home News FIDIO: Àwọn Èèyàn Oyo Fì Ìbò Sọ̀rọ̀ Pé Ìjọba Ajimobi Kò Dára...

FIDIO: Àwọn Èèyàn Oyo Fì Ìbò Sọ̀rọ̀ Pé Ìjọba Ajimobi Kò Dára — Ladoja

1579
0
Osi Olubadan ti ilẹ Ibadan, to tun jẹ gomina tẹlẹ ni ipinlẹ Oyo, Senetọ Rashidi Ladọja ti salaye pe, inu Ajimọbi dun pe o fidi rmi ninu ibo sile asofin agba to kọja.
Ladọja ni nigba ti Ajimọbi ri pe ọpọ eeyan lo fidi rẹmi lasiko ibo naa, wa gba lati maa se bii Jagaban ti ipinlẹ Oyo.
O fikun pe, ohun ti ko kan Ajimọbi lo n da si lasiko to fi wa lori oye, idi si ree ti awọn eeyan ipinlẹ Oyo se fi ibo sọrọ̀ fun pe, ijọba rẹ ko se daada.

Previous articleDibu Ojerinde’s Son Advises Muslims On Love, Sacrifice
Next articleIbadan Airport Records 13,305 Passengers Between January And March 2019

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here