Home News Ọdún 1940 Ni Wọ́n Ti Ń Sin Òọ̀nì Ilé Delesolu Ní Ìbàdàn

Ọdún 1940 Ni Wọ́n Ti Ń Sin Òọ̀nì Ilé Delesolu Ní Ìbàdàn

1975
0

Ìgbẹ́ ọ̀ọ̀nì yì ti di oògùn ara lílé fáwọn èèyàn kan.

Oloye Raufu Yesufu to jẹ mọ́gàjí ilé Delesolu ti wọn ti n sin ọọni yii ni Ibadan ṣalaye fun BBC Yorùbá pé àwọn baba nla wọn lo bẹrẹ sinsin ọọni naa bi èran ọ̀sìn ninu ilé ni 1940.

Google search engine

Ọọni naa ti wa di eyi ti awọn babalawo ati oniṣegun n mu adìyẹ to tobi wa fun wa fi tọrọ nkan ati lati wa dupẹ fún.

Loju àwọn ọmọ inu ile Delesolu, ‘Àṣà ni kìí ṣe ẹ̀sìn rara’ tori wọn gba pe kò si awo kan láwo ẹ̀wà lori ọọni naa.

Ilé Delesolu ti ọọni yii n gbe sẹ̀ wá lati Ijẹru de agbegbe Oje nilu Ibadan ni ipinlẹ Oyo ni guusu Naijiria.

Previous articleK1, Ayefele, Osupa, Obesere, Currency, Others To Sing For Olubadan At 90
Next articleOyo 2019: NLC Throws Weight Behind Eniade’s Governorship Bid

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here